Main public logs
Appearance
Combined display of various logs. You can select the log type, the user name (case-sensitive except for the first letter) of the acting user, and/or the affected page (full name required, case-sensitive except for the first letter).
- 16:00, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gina Bennett from Proofreading to Published
- 16:00, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gina Bennett/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2022/Àwọn Olùdíje/Gina Bennett")
- 16:00, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gina Bennett/yo (Created page with "Mo lo gbogbo ìgbé ayé mi lórí ìrànìyàn lọ́wọ́ láti ní ìmọ̀, mo rí ìkópa mi pẹ̀lú WMF gẹ́gẹ́ bí àlékún ìfẹ́ síi. Iṣẹ́ mi nílé àti lẹ́yìn odi la ojú mi sí àìṣedọ́gbándọ́gba lórí ànfàní ìkẹ́kọ̀ọ́ àti àwárí ọ̀yàyà sí iṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ènìyàn tó ń ṣiṣẹ́ pẹ́ẹ̀pẹ̀ẹ̀pẹ́, àjọpín àkóónú ẹ̀kọ́ àti àjùmọ̀sepọ̀ lórí àwọn ikọ̀...")
- 16:00, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gina Bennett/1/yo (Created page with "Mo lo gbogbo ìgbé ayé mi lórí ìrànìyàn lọ́wọ́ láti ní ìmọ̀, mo rí ìkópa mi pẹ̀lú WMF gẹ́gẹ́ bí àlékún ìfẹ́ síi. Iṣẹ́ mi nílé àti lẹ́yìn odi la ojú mi sí àìṣedọ́gbándọ́gba lórí ànfàní ìkẹ́kọ̀ọ́ àti àwárí ọ̀yàyà sí iṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ènìyàn tó ń ṣiṣẹ́ pẹ́ẹ̀pẹ̀ẹ̀pẹ́, àjọpín àkóónú ẹ̀kọ́ àti àjùmọ̀sepọ̀ lórí àwọn ikọ̀...")
- 15:59, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Shani Evenstein Sigalov/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2022/Àwọn Olùdíje/Shani Evenstein Sigalov")
- 15:59, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Shani Evenstein Sigalov/4/yo (Created page with "Wọ́n bu ọlá láti dìbò yàn mí fi sin ẹgbẹ́, pẹ̀lú ìrètí láti tẹ̀síwájú iṣẹ́ lórí àwọn ọ̀rọ̀ tó se kókó.")
- 15:58, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Shani Evenstein Sigalov/3/yo (Created page with "Gẹ́gẹ́ bí Igbákejì Alága ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́, mo gbájúmọ́ ìgbélárúgẹ gbangba-làsá-ń-ta ìgbìmọ̀ fún ìdánmọ́rán ìbásepọ̀ Movement-Foundation-Board dáadáa, l'àgbékalẹ̀ àti ìdarí Community Affairs Committee, ó gbájúmọ́ àtúnṣe ìpinnu àti àkóyawọ́ (later UCoC), àti òfin ìjàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn. Bákan náà ó kópa níbi Ìgbìmọ̀ Adelé fún yíyàn Ọ̀gá Àgbà titun...")
- 15:58, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Shani Evenstein Sigalov/2/yo (Created page with "Mo gbìyànjú láti dí àlàfo ẹ̀yà, èdè, ìṣesí àwùjọ nípasẹ̀ iṣẹ́ mi pẹ̀lú àwọn ẹ̀kọ́ tí mo kọ́ lórí Wikipedia àti Wikidata, àkókò irú ẹ̀ lágbàyé. Lásìkò ìkẹ́kọ̀ọ́ gboyè ọ̀jọ̀gbọ́n (Education - Technology & Learning) mo ṣèwádìí Semantic Web, ní pàtó Wikidata.")
- 15:58, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Shani Evenstein Sigalov/yo (Created page with "Olùdánilẹ́kọ̀ọ́, olùkọ́, olùwádìí àti olùpè fún ìmọ̀ ọ́fẹ̀ẹ́ gbígbájúmọ́ Outreach (Education, GLAM, Libraries, Medicine, WikiWomen, Wikidata), Ìṣèlú àti ààtò ni láti ṣàṣeyọrí àwọn àfojúsùn wa lórí ìmọ̀ ọ̀fẹ́ fún gbogbo ènìyàn.")
- 15:58, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Shani Evenstein Sigalov/1/yo (Created page with "Olùdánilẹ́kọ̀ọ́, olùkọ́, olùwádìí àti olùpè fún ìmọ̀ ọ́fẹ̀ẹ́ gbígbájúmọ́ Outreach (Education, GLAM, Libraries, Medicine, WikiWomen, Wikidata), Ìṣèlú àti ààtò ni láti ṣàṣeyọrí àwọn àfojúsùn wa lórí ìmọ̀ ọ̀fẹ́ fún gbogbo ènìyàn.")
- 15:57, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Kunal Mehta/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2022/Àwọn Olùdíje/Kunal Mehta")
- 15:57, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Kunal Mehta/2/yo (Created page with "Ọ̀kan gbòógì lára iṣẹ́ WMF ni ìgbélárúgẹ àti ṣíṣe itọju ìmọ̀ ẹ̀yà, pàtàkì ni kí ìgbìmọ̀ sàgbéjáde ìpinnu tó dára lórí àwọn ọ̀tun ìmọ̀ àti àwọn ohun pàtàkì-jùlọ. Gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan tó ní ìrírí ìdàgbàsókè, pínpín kiri, ṣíṣe itọju ẹ̀yà tó bá àmúyẹ aláìlẹ́gbẹ́ Wikimedia mu, mo gbàgbọ́ pé ìrírí mi àti ìwòye lè ran ìgbìmọ̀ àti WMF lọ́wọ́ l...")
- 15:56, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Kunal Mehta/yo (Created page with "Mo ti jẹ́ Wikimedian lát'ọdún 2007, mo sì jẹ́ òṣìṣẹ́ WMF tẹ́lẹ̀ f'ọ́dún mẹ́jọ (see full biography). Láti àwọn ojúse méjéèjì wọ̀nyí, mo ti jàǹfààní àgbọ́yé tó nípọn lórí ìmọ̀ tó nílò àti òtítọ́ ìgbésẹ̀ náà. Àwọn afinúfẹ́dọ̀ ṣiṣẹ́ sagbátẹrù àlàáfíà àti ìdúróre àwùjọ, ẹ̀ka àti ìjọra òṣìṣẹ́ WMF nítorína mo ti ṣiṣẹ́ láti sol...")
- 15:56, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Kunal Mehta/1/yo (Created page with "Mo ti jẹ́ Wikimedian lát'ọdún 2007, mo sì jẹ́ òṣìṣẹ́ WMF tẹ́lẹ̀ f'ọ́dún mẹ́jọ (see full biography). Láti àwọn ojúse méjéèjì wọ̀nyí, mo ti jàǹfààní àgbọ́yé tó nípọn lórí ìmọ̀ tó nílò àti òtítọ́ ìgbésẹ̀ náà. Àwọn afinúfẹ́dọ̀ ṣiṣẹ́ sagbátẹrù àlàáfíà àti ìdúróre àwùjọ, ẹ̀ka àti ìjọra òṣìṣẹ́ WMF nítorína mo ti ṣiṣẹ́ láti sol...")
- 15:55, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Egbe Eugene Agbor from Proofreading to Published
- 15:55, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Egbe Eugene Agbor/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2022/Àwọn Olùdíje/Egbe Eugene Agbor")
- 15:55, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Egbe Eugene Agbor/2/yo (Created page with "Mo fẹ́ mójú tó ìṣòro àìtó-aṣojú àwọn àwùjọ àti ìkópa wọn nínú àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia pàápàá ibùgbé èdè pẹ̀lú ìlànà ìgbésẹ̀ ní ṣẹpẹ́, mo fẹ́ rí ọpọlọpọ àwọn àwùjọ láti tẹ̀lé àwọn ìmọ̀ràn Wikimedia nípa àwọn òótọ́ wọn, láti rí àlékún àtìlẹyìn fí sàmúsẹ àfojúsùn wọn.")
- 15:55, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Egbe Eugene Agbor/yo (Created page with "Mo darapọ̀ mọ́ àjọṣepọ̀ yìí lọ́dún 2016 gẹ́gẹ́ bíi developer àti oníṣẹ́ tó ń ṣiṣẹ́ lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe bíi Wikidata, Commons àti Wikipedia pẹ̀lú àwọn tó kù. Àfojúsùn mi àkọ́kọ́ ni láti máa mú ìdàgbàsókè báwọn irinṣẹ́ láti ran àìtó-aṣojú àwọn àwùjọ lọ́wọ́ dásí àwọn iṣẹ́-àkànṣe yìí láti sọ idásí dẹ̀rọ̀. Mo ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ...")
- 15:55, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Egbe Eugene Agbor/1/yo (Created page with "Mo darapọ̀ mọ́ àjọṣepọ̀ yìí lọ́dún 2016 gẹ́gẹ́ bíi developer àti oníṣẹ́ tó ń ṣiṣẹ́ lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe bíi Wikidata, Commons àti Wikipedia pẹ̀lú àwọn tó kù. Àfojúsùn mi àkọ́kọ́ ni láti máa mú ìdàgbàsókè báwọn irinṣẹ́ láti ran àìtó-aṣojú àwọn àwùjọ lọ́wọ́ dásí àwọn iṣẹ́-àkànṣe yìí láti sọ idásí dẹ̀rọ̀. Mo ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ...")
- 15:53, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Joris Darlington Quarshie from Proofreading to Published
- 15:49, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Joris Darlington Quarshie/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2022/Àwọn Olùdíje/Joris Darlington Quarshie")
- 15:49, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Joris Darlington Quarshie/3/yo (Created page with "Lórí àwọn ìrírí mi tẹ́lẹ̀ nínú òfin ará ìlú, mo fẹ́ dásí ìsamùsẹ àwọn ètò tó wà ní ìbámu ìsàmúsẹ ìlànà ìgbésẹ̀ àti ìgbìmọ̀ káríayé lójúnà à ti rí dájú pé ìsedọ́gbándọ́gba wà fún gbogbo ènìyàn.")
- 15:49, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Joris Darlington Quarshie/2/yo (Created page with "Oṣù díẹ̀ sẹ́yìn, àfojúsùn mi àkọ́kọ́ ni gbígbé irinsẹ́ Wikimedia dé ẹsẹ̀ kùùkú àti àkànṣe iṣẹ́ lójúnà à ti lọ́wọ́ sí yíyanjú àwọn ọ̀rọ̀ tó láàáyẹ léyìí tó ní í ṣe pẹ̀lú àìtó-aṣojú àwọn àwùjọ káríayé. Ọ̀kan lára èròńgbà mi ni láti ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú àsopọ̀ àwọn ẹ̀ka Wikipedia àti àwọn àwùjọ lójúnà àti sàgbékalè àwọn ohun èl...")
- 15:48, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Joris Darlington Quarshie/yo (Created page with "Mo ti jẹ́ olùtọ́nisọ́nà, olùsọdẹ̀rọ̀ pẹ̀lú aṣaájú àwùjọ àti ṣíṣe àtìlẹyìn ìmọ̀ sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àìtó-aṣojú àwọn àwùjọ àti olùfarajìn Wikimedia nílẹ̀ Áfíríkà ní pàtó. Mo máa ń fojú sọ́nà láti àlékún ìrànwọ́ sáwọn àwùjọ tóní àìtó-aṣojú àti ìdásí káríayé.")
- 15:48, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Joris Darlington Quarshie/1/yo (Created page with "Mo ti jẹ́ olùtọ́nisọ́nà, olùsọdẹ̀rọ̀ pẹ̀lú aṣaájú àwùjọ àti ṣíṣe àtìlẹyìn ìmọ̀ sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àìtó-aṣojú àwọn àwùjọ àti olùfarajìn Wikimedia nílẹ̀ Áfíríkà ní pàtó. Mo máa ń fojú sọ́nà láti àlékún ìrànwọ́ sáwọn àwùjọ tóní àìtó-aṣojú àti ìdásí káríayé.")
- 15:45, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Tobechukwu Precious Friday (Tochiprecious) from Proofreading to Published
- 15:44, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Abdermane Abakar Brahim from Proofreading to Published
- 15:44, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Abdermane Abakar Brahim/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2022/Àwọn Olùdíje/Abdermane Abakar Brahim")
- 15:43, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Abdermane Abakar Brahim/yo (Created page with "Mo darapọ̀ lọ́dún 2018 gẹ́gẹ́ bí olùfarajìn lórí Wikipedia, láti ibẹ̀ ni mo ti gbé ojúṣe tèmi nípa ṣíṣe iṣẹ́ lórí iṣẹ́-àkànṣe bíi Wikipedia, Commons, Wiki Loves Africa, Wiki Kouman àti àwọn tó kù. Àfojúsùn mi àkọ́kọ́ ni láti sin àwọn ìletò tí yóò wúlò fún ìmọ̀ nítorí ó ní ènìyàn tí ó wà nínú àìní. Mo kẹ́kọ̀ọ́ láti ṣé àjọpín pẹ̀lú àwọn àwùjọ nípa...")
- 15:43, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Abdermane Abakar Brahim/1/yo (Created page with "Mo darapọ̀ lọ́dún 2018 gẹ́gẹ́ bí olùfarajìn lórí Wikipedia, láti ibẹ̀ ni mo ti gbé ojúṣe tèmi nípa ṣíṣe iṣẹ́ lórí iṣẹ́-àkànṣe bíi Wikipedia, Commons, Wiki Loves Africa, Wiki Kouman àti àwọn tó kù. Àfojúsùn mi àkọ́kọ́ ni láti sin àwọn ìletò tí yóò wúlò fún ìmọ̀ nítorí ó ní ènìyàn tí ó wà nínú àìní. Mo kẹ́kọ̀ọ́ láti ṣé àjọpín pẹ̀lú àwọn àwùjọ nípa...")
- 15:40, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Lionel Scheepmans from Proofreading to Published
- 15:39, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Lionel Scheepmans/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2021/Àwọn Olùdíje/Lionel Scheepmans")
- 15:39, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Lionel Scheepmans/3/yo (Created page with "Bó se jẹ́ pé ó lè l'ẹgbẹ̀ta òṣìṣẹ́ láti ọna jíjìn, ó ṣòro láti mójú tó àjọ náà. Dípò àlékún Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́, yóò dára kí wọ́n dín òṣìṣẹ́ kù àti ìkówójọ lèyí tí àwọn oníròyìn kò sọ ní dáradára.")
- 15:38, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Lionel Scheepmans/2/yo (Created page with "Bẹ̀rẹ̀ láti ìwádìí mi lórí Àjọṣepọ̀ Wikimedia Mo tún jiyàn pé ọ̀pọ̀ owó jẹ́ wàhálà sí èrò wa lórí pínpín ìmọ̀. O mú àlékún bá òǹkà àwọn òṣìṣẹ́ láìbìkítà àwọn olóòtù, nígbà táwọn tó fún àjọ lówó ò bá le fi àsìkò wọn fún àwọn iṣẹ́-àkànṣe.")
- 15:36, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Lionel Scheepmans/yo (Created page with "Bó tilẹ̀ jẹ́ pé mo jẹ́ olùdíje mo tako àwọn ìlànà ọ̀làjú tó f'àwọn díẹ̀ lágbára dípò tí tẹ̀lé ìpinnu àpéjọ pẹ̀lú àjọsepọ̀ àti ìfìfẹ́hàn àwọn ènìyàn àwùjọ wa. Gẹ́gẹ́ bí àwọn onígbọ̀wọ́ nínú àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia, mo gbàgbọ́ pe àjọ onígbọ̀wọ́ ọ̀hún lè sàmúsẹ pẹ̀lú fìdí ìpinnu àwùjọ múlẹ̀.")
- 15:36, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Lionel Scheepmans/1/yo (Created page with "Bó tilẹ̀ jẹ́ pé mo jẹ́ olùdíje mo tako àwọn ìlànà ọ̀làjú tó f'àwọn díẹ̀ lágbára dípò tí tẹ̀lé ìpinnu àpéjọ pẹ̀lú àjọsepọ̀ àti ìfìfẹ́hàn àwọn ènìyàn àwùjọ wa. Gẹ́gẹ́ bí àwọn onígbọ̀wọ́ nínú àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia, mo gbàgbọ́ pe àjọ onígbọ̀wọ́ ọ̀hún lè sàmúsẹ pẹ̀lú fìdí ìpinnu àwùjọ múlẹ̀.")
- 15:31, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Tobechukwu Precious Friday (Tochiprecious)/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2021/Àwọn Olùdíje/Tobechukwu Precious Friday (Tochiprecious)")
- 15:28, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Tobechukwu Precious Friday (Tochiprecious)/yo (Created page with "Mo di Wikimedian lọ́dún 2017, pẹ̀lú àjùmọ̀pọ̀ dá ẹgbẹ́ User Group kan sílẹ̀ lọ́dún 2018, mo di Wikimedian in Residence tí mo sì ti ń ṣàwọn ọ̀kan-ò-jọ̀kan àwọn iṣẹ́-àkànṣe pẹ̀lú Àwọn Àwùjọ Wikimedia tí mo ń gbìyànjú idàgbàsókè àwọn àwùjọ titun mìíràn. Mo jẹ́ ẹnìkan tó gbàgbọ́ gidigidi nínú ìfinúfẹ́dọ̀sini, ètò àpéjọpọ̀ àwùjọ, onírúurú àti ìfisí à...")
- 15:28, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Tobechukwu Precious Friday (Tochiprecious)/1/yo (Created page with "Mo di Wikimedian lọ́dún 2017, pẹ̀lú àjùmọ̀pọ̀ dá ẹgbẹ́ User Group kan sílẹ̀ lọ́dún 2018, mo di Wikimedian in Residence tí mo sì ti ń ṣàwọn ọ̀kan-ò-jọ̀kan àwọn iṣẹ́-àkànṣe pẹ̀lú Àwọn Àwùjọ Wikimedia tí mo ń gbìyànjú idàgbàsókè àwọn àwùjọ titun mìíràn. Mo jẹ́ ẹnìkan tó gbàgbọ́ gidigidi nínú ìfinúfẹ́dọ̀sini, ètò àpéjọpọ̀ àwùjọ, onírúurú àti ìfisí à...")
- 15:26, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gilbert Ndihokubwayo from Proofreading to Published
- 15:25, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gilbert Ndihokubwayo/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2021/Àwọn Olùdíje/Gilbert Ndihokubwayo")
- 15:25, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gilbert Ndihokubwayo/yo (Created page with "Èmi Gilbert Ndihokubwayo, alájùmọ̀pọ̀dá ígbèsẹ̀ Wikimedia sílẹ̀ nílẹ̀ Burundi, mo ti ń kópa tí mo ń siṣẹ̀ olùfinúfẹ́dọ̀ iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia láti ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2019. Mo dá sí àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia, mo ti ṣètò àti àmójútó àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia bíi Wiki Loves Áfíríkà, Wiki Loves Earth, Áfíríkà Wiki Challenge, Editathons àti ìlanilọ́yẹ̀. Báyìí mo ń...")
- 15:25, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Gilbert Ndihokubwayo/1/yo (Created page with "Èmi Gilbert Ndihokubwayo, alájùmọ̀pọ̀dá ígbèsẹ̀ Wikimedia sílẹ̀ nílẹ̀ Burundi, mo ti ń kópa tí mo ń siṣẹ̀ olùfinúfẹ́dọ̀ iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia láti ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2019. Mo dá sí àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia, mo ti ṣètò àti àmójútó àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia bíi Wiki Loves Áfíríkà, Wiki Loves Earth, Áfíríkà Wiki Challenge, Editathons àti ìlanilọ́yẹ̀. Báyìí mo ń...")
- 15:15, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Mike Peel from Proofreading to Published
- 15:15, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Mike Peel/2/yo (Created page with "Mo ti di oníṣẹ́ Wikimedia láti ọdún 2005 pẹ̀lú ìdásí káàkiri Wikipedia, Wikidata, Commons, Wikisource, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ lọ́wọ́ pẹ̀lú aláìlọ́wọ́ àti lílo irinsẹ́ ọwọ́ díẹ̀. Lápá ààtò, mo kún ẹ̀dáwó Wikimedia UK bẹ́ẹ̀ mo jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Wiki Movimento Brazil. Mo tí jẹ́ ikọ̀ olùpín owó fún ọdún mẹ́rin, báyìí mo jẹ́ ìgbìmọ̀ ẹkùn ìyọ̀ǹda owó ìrànwọ...")
- 15:14, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Mike Peel/1/yo (Created page with "Mo fẹ́ mú òye Wikimedia mi àti ìrírí ìgbé ayé mi wá sí ìgbìmọ̀ WMF lákòókò àyípadà, pẹ̀lú ígbèsẹ̀ ìsàmúsẹ ìlànà àti ìgbìmọ̀ káríayé tó ń bọ̀. Mo fẹ́ rí àjùmọ̀sepọ̀ WMF si lórí wiki nílànà wiki pẹ̀lú àtìlẹyìn iṣẹ́ ìmọ̀-ẹrọ dáadáa àti ohun èlò fún àtìlẹyìn ìmọ̀ ọlọ́pọ̀ èdè ófẹ̀ẹ́ káàkiri gbogbo àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia. Mo tún f...")
- 15:14, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Mike Peel/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2021/Àwọn Olùdíje/Mike Peel")
- 15:14, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Mike Peel/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2021/Àwọn Olùdíje/Mike Peel")
- 15:09, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs changed the state of Yoruba translations of Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Farah Jack Mustaklem from Proofreading to Published
- 15:08, 21 June 2022 SOyeyele (WMF) talk contribs created page Translations:Wikimedia Foundation elections/2022/Candidates/Farah Jack Mustaklem/Page display title/yo (Created page with "Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2021/Àwọn Olùdíje/Farah Jack Mustaklem")
Retrieved from "https://meta.wikimedia.org/wiki/Special:Log/SOyeyele_(WMF)"